top of page

Resources For Yorùbá Learners

Yorùbá Textbooks

Reference Texts

Jẹ́ K'á Sọ Yorùbá

Antonia Y. Fọlárìn Schleicher

Yale University Press

Jẹ́ K’Á Ka Yorùbá

Antonia Y. Fọlárìn Schleicher

Yale University Press

Yorùbá Yé mi

Fehintola Mosadomi Ph.D.
University of Texas, Austin

 

Colloquial Yoruba

Antonia Schleicher

Routledge Press, London

Aláwìíyé

Ìwé Kìíní  (Àtúnṣe Kẹ́rin)

J.F Ọdúnjọ Pẹ̀lú Àfikún láti ọwọ́ Túnji Ọ̀pádọ̀tun

Longman

Please reload

Yoruba Modern Practical Dictionary

Kayode J. Fakinlede.

Hippocrene Books Inc.

Yoruba Newspaper Reader

Antonia Y. Folarin Schleicher

Please reload

Literary Texts

Erée Géle

Ọgbọ́n orí tí ó péye àti àròjinlẹ̀ tó pinmirin ní Òǹkọ̀wé Ṣegun Ṣóẹ̀tán fi gbé ìwé ìtàn àròsọ yìí kalẹ̀. Ojúlówó èdè Yorùbá ní ó sí fi pèèlò rẹ̀. Àwọn ẹwà èdè Yorùbá ló ń ṣe gbérùmi-sọ̀mí nínú ìwé náà. Ó yá, ẹ gbà kẹ́ẹ tọ́ọ wò. Ire o!

Oyin inú Àpáta

Ìwe àkàgbádùn ní Oyin Inú Àpàta. Ó jẹ́ ìwé ìtàn àròsọ tí Ọ̀mọ̀wé Olúṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán fí ọgbọ́n inú àti ète ìmọ́ lítíréṣọ̀ gbé kalẹ̀. Ìwé yìí wúlò fún ẹni gbogbo, yálà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga girama tàbí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yunifásitì.

Please reload

bottom of page